2 Corinthians 6:14

Má ṣe dàpọ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́

14Ẹ má ṣe fi àìdọ́gba dàpọ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́: nítorí ìdàpọ̀ kín ni òdodo ní pẹ̀lú àìṣòdodo? Ìdàpọ̀ kín ni ìmọ́lẹ̀ sì ní pẹ̀lú òkùnkùn?
Copyright information for YorBMYO